Sasa crisis in Ibadan: Ìbànújẹ́ ńlá ni ìṣẹ̀lẹ̀ Sasa jẹ́ fún mi - Makinde
Makinde lo kede bẹẹ ninu fọran kan to fi lede loju opo Twitter rẹ, eyii to fi ba awọn eeyan ipinlẹ naa sọrọ.
Gomina ọhun sọ pe "mo ṣabẹwo si ọja Sasa ati Ojo ni ijọba ibilẹ Akinyele, mo si ri awọn ti ọrọ naa kan, o jẹ ohun to ba mi ninu jẹ gidi pe awọn eeyan kan ba iṣẹlẹ naa lọ."
"Ṣugbọn mo fẹ fi da yin loju pe, gbogbo ohun to yẹ ni a maa ṣe lori iṣẹlẹ naa, mo ti gbe iwadii dide lati mọ ohun to fa iṣẹlẹ naa, mo ṣi ṣeleri fun yin pe gbogbo awọn to lọwọ ninu rogbodoyan ọhun ni yoo foju wina ofin."
- Gómìnà Borno fi ọkọ̀ àti N13.9m dá Dókítà Akinbode lọ́lá fún ìṣẹ́ takuntakun ní iléèwòsàn ìjọba ní Borno
- Gbogbo àwọn tó lọ́wọ́ nínú rògbòdìyàn tó wáyé ní Sasa ni yóò fojú winá òfin - Seyi Makinde
- "Orin Shanku, Gbese, Já paa, Jesu máa párò lọ, inú Ọlọ́run kò dùn sí i - Bola Are
- Bí àlááfíà yóò ṣe wà láàrin Fulani àti Yorùbá ni Ooni bá lọ sọ́dọ̀ Buhari- Ààfin Ile Ife
- Gómìnà Borno fi ọkọ̀ àti N13.9m dá Dókítà Akinbode lọ́lá fún ìṣẹ́ takuntakun ní iléèwòsàn ìjọba ní Borno