Coronavirus: Àwọn ìpèníjà márùn ún tó wà lórí pínpín abẹ́rẹ́ ajẹ́sara àrún Coronavirus
Lati igba ti arun Coronavirus ti bu jade ni nnkan bi ọdun kasẹyin niluu Wuhan, lorilẹ-ede China ni awọn onimọ kaakiri agbaye ti n wa ọna ababyọ si arun naa.
Lara awọn ọna abayọ ti wọn wa ni abẹrẹ ajẹsara, eyii ti yoo lagbara lati koju arun ọhun.
Ṣugbọn bawo ni wọn ṣe lee pin abẹrẹ yii ti yo fi kari gbogbo agbaye, ati pe ki ni awọn ipenija to rọ mọ pinpin abẹrẹ naa?
- Ṣé ẹ rántí àkọ́lé àwọn ìwé àkàgbádùn yìí?
- Wo ọ̀rọ̀ tí Asiwaju Bola Tinubu fi síta lórí ìṣòro ètò àbò Nàìjíríà
- Mi ò to iṣẹ́ Regina Daniels rárá kí n tó fẹ́ ẹ láàrin ọ̀sẹ̀ mẹ́ta, mo sì tún le fẹ́ ìyàwó míì - Ned Nwoko
- Àyà mi já nígbà tí Ganduje rọ Sanusi lóyè Emir Kano tó fi Bayero síi, ṣùgbọ́n...- Ooni Ile Ife
Ipenija akọkọ ni pe awọn eeyan gbọdọ gbagbọ ninu abẹrẹ naa pe o lagbara lati koju arun Covid-19, ati pe o le fun wọn ni alaafia.
Bakan naa ni awọn ti yoo maa pin abẹrẹ naa fun awọn eeyan ilu ni lati jẹ awọn oṣiṣẹ eto ilera to kọṣẹ mọṣẹ.
Wo fidio yii fun alaye kikun lori awọn ipenija ti abẹrẹ ajẹsara Covid-19 yoo dojukọ ati awọn ọna abayọ sii.