Covid-19 60seconds: Ṣé ìjìnà síra-ẹni ṣe paàtàkì lẹ́yìn lílo ìbòmú?
Láti ìgbà ti ààrùn Corornavirus ti bẹ̀rl lórílẹ̀-èdè Naijiria ni oníruuru iroyin ti n tan kalẹ.
Laipẹ yìí ni gómìnà ìpínlẹ̀ kan ní bi ènìyàn ba ti lo ìbòmu-bẹnu, kò nilo láti tèlé àsà ìjìnà si ara ẹni.
Sùgbọ́n ìwádìí fi yẹni pé èyí kìí ṣe òòtọ rára nítori pé titèlé gbogbo òfin to le dènà ààrun Corornavirus ṣe patakì.
Ẹkunrẹrẹ alaye ree lori igbesẹ to tọna