Ṣé fífi òrí pa ọwọ́ rẹ leè dáàbò bò ọ́ lọ́wọ́ Coronavirus?

Àkọlé fídíò, Ṣé fífi òrí pa ọwọ́ rẹ leè dáàbò bò ọ́ lọ́wọ́ Coronavirus?

Lẹyin ti fidio kan jade lori itakun agbaye, nibi ti awọn kan ti n fi ori pa ọwọ wọn lati dena arun Coronavirus.

Ọpọ eeyan lo n ti gbiyanju ati ṣe bẹ naa lọna ati le daabo bo ara wọn lọwọ arun naa.

Ṣugbọn, ṣe fifi ori pa ọwọ, imu tabi ara ẹni le daabo bo eeyan lọwọ arun yii?

BBC Yoruba tu pẹrẹpẹrẹ bi ọrọ ọhun ṣe jẹ.