Oxford English Dictionary: 'Àwọn ọ̀rọ̀ Nàìjíríà ti wọ́n fi kún un lọ́dun 2020

Ní ọdun 2020 ni Oxford English Dictionary ṣe afikún àwón ọ̀rọ̀ tuntun omíràn sínú ìwé náà.

Awọn ọ̀rọ̀ náà to jẹyọ nínú èdè Yòrúba, Hausa, Pidgin.

Awọn ọ̀rọ̀ náà ni ìtumọ àti bi wọ́n se ń sọ nínú èdè gẹ́ẹ̀sì, Buka / tẹria, guber, agric, ember Months, next tomorrow, Kannnywood.

Sef, chop, chop-chop, to eat money, barbing, salon, gist, to gist, put to bed, tokunbo, to rub minds àti àwọn ǹkan míran.

Oxford lóri ayelujara rẹ̀ sàlàyé pé bi Naijiria ṣe n fi kun èdè Gẹ̀ẹ́sì ju gbogbo àwọn èdè àgbáye míràn lọ.

Ilé iṣẹ́ náà ni àwọn lo lárá ọ̀rọ̀ ti onkowe Naijiria kan Chimamanda Ngozi Adichie sàlàye pé àwọn èdè ti òun kọ wà lárá ìrírí to ti ri ni Naijiria.

Oxford ni gẹ́gẹ́ bi Chimamanda ṣe sọ, ìgbàgbọ́ wà pé yóò fi iyọ si èdè Gẹ̀ẹ́sí gẹ́gẹ́ bi àwọn ṣe n koju mọ sísọ èdè gẹ̀ẹ́si àye òde òní.

Bí àwọn ọ̀rọ̀ náà àti ìtumọ wọ́n ṣe lọ rèé nínú Iwe ìtumọ Oxford English Dictionary