Christmas: Jesu ni ọjọ́ ọ̀la àti ibi ìyanu mi- Jaga
Ibanujẹ àti aisan dopin laye yin lorukọ Jesu- Jaga
Olorin Emi, Testimony Jaga to ṣe ọmọ alade wura to logo kọrin keresi loriṣiiriṣii fun igbadun gbogbo yin.
- 'Ìbọn ló yẹ kí n máa gbé fi jẹun ṣùgbọ́n Ọlọ̀run gbé mi ga'
- Ṣé ẹ ti ra fìlà ọdún? Dárúkọ ọjà Kérésí kan tí ẹ̀yin ti rà
- Ibi tí o bá dágbére fún ẹbí àti ará ní kí wọ́n ti ba ọ lásìkò ọdún Kérésì yìí- Akọ́ṣẹ́mọ́ṣẹ́
- Bayìí ni àwọn ọlọpàá Akure ṣe ko àwọn ará ìlú ti o ji ẹrù ni sọọsi Sotitobirẹ
- Ọmọ ogún ọdún kan tún di àwátì nílùú Akurẹ nípìnlẹ́ Ondo- PPRO
Adura pọ lẹnu Testimony Jaga, o fede fọ wure fawọn eniyan pe ọdun keresi a yabo.