Ìjàmbá Eko: Ṣúnkẹrẹ fàkẹrẹ gba òpópónà Berger kan torí ìjàmbá ọkọ̀

Iye eeyan to padanu ẹmi wọn ninu ijamba ọkọ to waye lori afara Otedola lopopona Eko si Ibadan ko tii hande.
ijamba naa ṣẹlẹ lowurọ Ọjọru ọsẹ ninu eyi ti ọkọ agbepo kan ati ọpọlọpọ ọkọ akẹru atawọn ọkọ mii wa.

Lati owurọ ni ijamba naa ti fa ọpọlọpọ sunkẹrẹ fakẹrẹ ọkọ loju popo ni iha kinni ati iha keji ọna gan ti ijamba ko ti ṣẹlẹ tori ọpọlọpọ awakọ to n lọ lo dara duro lati woran.
Koda awọn arinrinajo to n lọ ọna jinjin ko lee ṣi kuro loju kan tori ijamba yii.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
- Ikú tó ń pa ojúgbà ẹni..., kí ni ìparí òwe náà?
- Bobrisky dárò pé EFCC gbé Mompha, ọ̀dọ́mọdé olówó tó ń lo aago ₦20m
- Mò ń dókòòwò láti pín ọrọ̀ mi yíká Nàíjíríà kí àdínkù leè bá ìṣẹ́ - Dangote
- Kí ló dé tí Ilé ẹjọ́ sún ìgbẹ́jọ́ Naira Marley sí ọ̀la?
- Kèǹgbè lílù ní Ilọrin rèé, orin ìgbéyàwó, àwàdà àti ẹ̀ẹ̀kẹ́ èébú
Bo tilẹ jẹ wi pe ẹkunrẹrẹ iroyin ko tii si nipa ijamba yii, ajọ to n ri si iṣẹlẹ pajawiri ni ipinlẹ Eko (LASMA) fi ọpọlọpọ ọrọ sita nipa rẹ, loju opo Twitter wọn.
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of X post, 1

End of X post, 2

End of X post, 3
Awọn oṣiṣẹ pajawiri ni awọn ti ko awọn ọkọ to wa loju ọna kuro bayii.
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of X post, 4
Ṣaaju, LASTMA gba awọn awakọ nimọran lati lọ gba awọn ọna abuda mii lọ si ibi ti wọn ba n lọ kawọn oṣiṣẹ le doola awọn to fara gba ati ki ọna le la.
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of X post, 5