Àwọn kan ń dunú, àwọn kan ń ṣe ìkìlọ̀ lórí èsì ìdìbò ààrẹ

Àkọlé fídíò, Àwọn kan ń dunú, àwọn kan ń ṣe ìkìlọ̀ lórí èsì ìdìbò ààrẹ

Ọpọlọpọ ọmọ Naijiria lo ti n fi ero wọn han lori esi idibo aarẹ Naijria ati ireti wọn lọwọ ijọba tuntun.

Ni olu ilu Ipinlẹ Oyo, Ibadan, awọn ara ilu ni inu wọn dun bi awọn kan si ṣe n fi ehonu han. Bẹẹni awọn miiran n kilọ fun ijọba tuntun naa lati ma fi ọrọ wipe awọn kan ba ilu jẹ da iṣẹ to yẹ ki wọn ṣe si ilu duro.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ sí: