World Cup 2018: Sweden 1- 0 South Korea

Nínú ìdíje tó ti wáyé lónìí, èyí ní àwọn agbábọ̀ọ̀lù tó fakọyọ tí ìkọ wọn fi gbégba orokè.

Nínú ìdíje láàrín Sweden àti South Korea, Andreas Granvist, ló gbá bọ́ọ̀lù sáwọn.

Ní ti ìdíje láàrín ikọ̀ àgbábọ́ọ̀lù Belgium àti Panama, ńkan kò rọgbọ fún orílẹ̀-èdè Panama to jẹ́ ìgbà àkọ́kọ́ wọn níyí nínú ìdíje ifé ẹ̀yẹ àgbáyé.

Ẹlẹ́sẹ̀ àyo ikọ̀ Belgium ju bọ́ọ̀lù sawọn Panama nínú ipele àkọ̀kọ́.

Mertens náà kò gbẹ́yìn nínú ìdíje tòní bí o se ran Belgium lọ́wọ́ láti jáwe olúbori.

Nínú ìdíjeTunisia àti England, àmi ayo meji sí ẹyọ kan ní ìdíje náà pari si nígba ti ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù England gbọ̀nà èbùrú yọ sí Tunsia ni o ku diẹ kí ìdíje pari