Baba Suwe: Fún ojú lóúnjẹ nípa àwọn gbajúmọ̀ òṣèré tó yọjú síbi ìsìnkú Baba Suwe

Oni, ọjọ karundinlọgbọn, oṣu Kje, ọdun 2021 ni babatude Omidina, ti ọpọ mọ si Baba Suwe wọ kaa ilẹ sun nile rẹ to wa ni Ikorodu, niluu Eko.

Awọn ẹbi, ọrẹ, aladugbo, to fi mọ awọn agba oṣere tiata Yoruba lo peju sibi eto isdinku adẹrinpoṣonu naa.

Ẹni ọdun mẹtalelọgọt\a ni Baba Suwe ko to dagbere faye lẹyin aisan ranpẹ gẹgẹ bii ohun ti ọkan lara awọn ọmọ rẹ okunri ṣalaye fu BBC.