Coronavirus Vaccine: Ṣé abẹrẹ àjẹsára ti wà fún àrùn COVID-19?
Lẹyin ti arun Coronavirus di tọrọ fọnkale lọpọ orilẹede kaakiri agbaye, ọpọ awọn eeyan lo ti bẹrẹ si n wa abẹrẹ ajẹsara arun naa.
Awọn kan tilẹ n wa ibi ti wọn ti lee ri abẹrẹ ajẹsara ọhun naa lori itakun agbaye.
Ṣugbọn o ṣeni lanu pe, gẹgẹ bi ọrọ ti ajọ to n risi eto ilera lagbaye WHO ṣe sọ, ko tii si abẹrẹ ajẹsara arun ọhun.
Bi ọrọ ṣe jẹ wa ninu fidio yii.
- Ìtàn Manigbagbe: Àwọn àjakalẹ-àrun to ti wáyé rí ṣáájú Coronavirus
- Yewande bí'mọ tuntun jòjòló, Mercy Aigbe pàdánù èèyàn rẹ̀, Toyin Abraham fèsì lórí aṣoju NCDC
- Bí àwọn sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ lórí rédíò ní Rwanda ṣe ń dánilẹ́kọ̀ọ́ nípa àrùn Coronavirus rèé
- Ìjọba yóò lo BVN àtàwọn ọ̀nà méjì míràn láti pín owó ìrànwọ̀ fún aráàlú