You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Fadeyi Oloro Yoruba Films: Mi ò kí ń ṣèèyàn burúkú tàbí Babaláwo bí ẹ ṣe mọ̀ mí nínú eré
"Emi Fadeyi Oloro, emi arisa ina ako tagiri ede werepe ti o nibi aa gbamu gbogbo ara ló fi ń jó 'ni. Ẹní mọ̀ mí ò kò mi, ẹni kò mí ò mọ̀ mí, èmi ati kékeré m'ojú ewé, sanpọna ò gbóògùn".
Baba Fadeyi Oloro gba alejo BBC Yoruba nile rẹ. O bu ẹnu atẹ lu nkan ti ọpọ eniyan n ro ti wọn si n sọ nipa rẹ.
- 'Sanwo-Olu kan ẹbí wa lábùkù, ijó ló kí mọ́lẹ̀ kàkà kó bá wà kẹ́dùn ikú Bamise'
- Ìjọba ìpínlẹ Eko ti lé àwọn ọmọ ẹgbẹ́ NURTW kúrò ní gáréèjì ọkọ̀
- Olubadan tuntun, Lekan Balogun yóò gbadé lòníì, wo bí ètò yóò ṣe lọ
- Lẹ́yìn tí wọ́n gba ipò alága NURTW lọ́wọ́ rẹ̀, MC Oluomo yapá kúró ní NURTW
- Ejò, alángbá 43 dédé yọjú lábẹ́ aṣọ onífàyàwọ́ ejo níbodè America, wo ohun tó kó pamọ̀ sábẹ́ asọ
- Taa ni Firdauz Abdullahi, ọmọbabìnrin Kano tí yóò di olorì tuntun fún Oluwo?
- Yàtọ̀ sí oorun àsùn-fọnfọn, wo àwọn ìdí tóo fi nílò ìbálòpọ̀ tó gbóná-giri
- Chidinma Ojuwu tó ń jẹ́jọ́ ikú Usifo Ataga gbadé obìnrin tó rẹwà jùlọ lẹ́wọ̀n! Ìdí rèé?
"Àwọn ọ̀tá fẹ́ kí n kú ni ṣùgbọ́n Ọ̀lọ́run mi ò jẹ́, ẹ ó bẹ̀ mi kúrò láyé ni". Fadeyi Oloro kẹnu bọ ọfọ tan ni pẹrẹwu gẹgẹ bo ṣe maa n ṣe ninu ere lai fi ọkan pe meji rara.
Ọfọ ṣi ki si baba lẹnu, o sọ ọ tan lo ni ohun ti di Pasitọ bayii ki a sọ nkan mii.
- Ṣé ó lòdì sí òfin Ọlọ́run kí Krìstẹ́ni jẹ Ọba ilẹ̀ Yorùba? Pásítọ̀ ìjọ Deeper Life sọ ìran tó rí tó fi gbà láti jẹ Ọba
- Wo Ọba Yorùbá méjì tó ń darí ìlú kanṣoṣo àmọ́ tí wọ́n kẹ̀yìn síra lórí ìjàgbara tí Sunday Igboho ń darí
- 'Hááà! Bamise mà jìyà o, ó l'óun á mu mi kúrò nílé àyágbé àmọ́ ó wá di ẹni tí wọ́n yọ pátá lára rẹ̀'