Agric Locust: Àwọn kokoro eṣú ti ba irè oko jẹ nílẹ̀ Afirika

Àkọlé fídíò, East Africa: Àwọn kokoro ti ba èrè oko jẹ nílẹ̀ Afirika
Kòkòrò eṣú
Àkọlé àwòrán, Àwọn agbẹ ni orilẹẹde Ethiopia ati Kenya fi igbe ta

Ai si ojo fun ọpọlọpọ igba ni Ila Oorun Ilẹ Afirika ti fa ki kokoro ajẹnirun ba ere oko awọn agbẹ jẹ ni ẹkun naa.

Nkan ko ṣe ẹnu ire fun awọn agbẹ lorilẹede Kenya, Ethiopia to fi mọ Yemen nitori esu to n ja ire oko.

Esu kan to miliọnu kokoro, ti o si ba awọn ere oko jẹ fun awọn agbẹ.

Amọ onimọ nipa eto ọgbin ti rọ awọn agbẹ lati ma lọ kuro ni ileto kan si omiran, ti kokoro ba ti ba ire oko wọn jẹ.