You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
BBC Gov Debates: Àwọ́n olùdíje ìpínlẹ̀ Ogun ṣe tan láti jíròrò
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 1
Ka wi i bẹẹ ka ba a bẹẹ niyi ọmọluabi. BBC Yoruba ṣeleri lati ṣagbekalẹ ifọrọwerọ gomina ni ipinlẹ Ogun o si ti de bayii.
Awọ̀n oludije meje ni yoo maa kopa nibi ipade ifọ̀rọ̀wérọ̀ naa gẹ́gẹ́ bi ipe to jade sita si awọn oludije ti awọn eniyan yan pe awọn fẹ ri nibi ifọrọwerọ naa.
Ṣaaju ọjọ oni, awọn akopa ti forukọ silẹ rẹpẹtẹ lori itakun ti BBC Yoruba fi silẹ loju opo wọn. Koda, itage ti to.
Gbogbo eto lo ti to bayii nibi gbọngan ipade naa eyi tii ṣe gbọngan igbalejo Oluṣẹgun Ọbasanjọ Library to wa ni ilu Abeokuta gẹgẹ bi awọn akopa ṣe ti bẹrẹ si ni fi orukọ silẹ.