‘ASUU da ìyanṣẹ́lódì dúró'

Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 1

Ìròyìn tó ń tẹ̀ wa lọ́wọ́lọ́wọ́ ní wí pé ẹgbẹ́ olùkọ́ àgbà ilé ẹ̀kọ́ gíga fásítì ASUU ti fagile iyanṣẹ́lódi oloṣumẹfa ti wọn gun lé.

Lonii, ọjọbọ, ọjọ keje oṣu keji ni èyí wáyé.

Ẹgbẹ ASUU fi ikede yi sita loju opo Twitter wọn

Ohun ta gbo ni pe ipinu lati mu iyanṣẹlodi naa wa si opin waye lẹyin ipade kan laarin ijọba ati awọn ọmọ gbẹ naa labuja.

Gẹgẹ bi ohun ti a gbo,awọn akẹkọ ati olukọ ile ẹkọ yoo pada si iṣẹ lọla.