Ìjọba Èkó: Àdínkù yóò wà fún ìgbòkègbodò ọkọ̀ ní Agége

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Èkó tí kéde pé òun yóò túbọ̀ mú adinku bá igbòkè gbodo ọkọ̀ lágbègbè Pen Cinema.

Ìjọba kéde ọ̀rọ̀ òhún nínú àtẹ̀jáde kan tí akowe àgbà ilé ìṣẹ̀ Irina gbé jáde, pé ìgbésẹ̀ yìí yóò fún ìjọba láǹfààní láti parí afárá Pen Cinema lásìkò tó yẹ.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: