Amòfin: Àwọn ẹrù kan wà tí kò yẹ nínú àpamọ́wọ́

Takọ tabo ló ń gbé Àpamọ́wọ́ lágbàáyé báyìí.

Gbogbo ìran, èdè àti ẹ̀yà ló ń fi Àpamọ́wọ́ kó ǹkan tó se pàtàkì sí wọn.

Bí ọ̀làjú sé ń dé ni Àpamọ́wọ́ àwọn ènìyàn se ń tóbi síi.

Kínní kò yẹ kó wà nínú Àpamọ́wọ́ rẹ?

Sùgbọ́n àwọn ẹrù kan wà tí kò bá òfin mu, tí à ń kó sínú àpamọ́wọ́ wa èyítí Ọlọ́pàá lè mú wa fún.

Ń jẹ́ kín lo kó sínú àpamọ́wọ́ rẹ?

Doyinsọ́lá Òdúkòmaiyà sọ àwọn ohun tó wà nínú àpamọ́wọ́ rẹ̀:

Asòfin James Ajibola sọ̀rọ̀ lórí àwọn ǹkan tí kò yẹ kó wà nínú àpamọ́wọ́ ẹni:

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Àwọn ọ̀nà tí á ń gbà gbé Àpamọ́wọ́ wa:

  • Pìpọ̀n sẹ́yìn
  • Fífà lọ́wọ́
  • Fífi kọ́ èjìká
  • Pípọ̀n sáyà
  • Fífi kọ́ ọrùn