You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Femi Falana, Endsars: Awolowo kò faàyè gba kí èèyàn máa yàgò fún Màálù nígboro
O yẹ ki a da gbogbo Maalu pada sibudo kan ni, kii ṣe pe ki wọn maa ringboro kiri- Femi Falana
Agba ogbontarigi agbẹjọro ni Naijiria, Femi Falan ni pe Ooṣa boo le gbemi, niṣe ni koo ṣe mi bi o se ba mi ni ọrọ eto aabo Naijiria de duro.
O di dandan ki ara ilu gbeja ara wọn tabi ki wọn dide ogun nigba ti ijoba Naijiria ti kuna lati pese aabo to yẹ ni ọrọ ti Falana fi sọri abẹwo rẹ.
- Mo ti mọ̀ pé mo ṣì máa 'Blow' lọ́jọ́ kan- Bàbá Lórí Irọ́
- Ṣé lóòtọ́ ni pé iṣẹ́ Àgbẹ̀ dára ju iṣẹ̀ Olùkọ́ lọ?
- Kílódé tí àwọn èèyàn ṣe ń gbé òkú pamọ̀ sílé fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún ní ìlú yìí?
- Ta ló sánwó ilé ìwòsàn Sóò bàtà Yorùbá tó dá sọ́rọ́ aláboyún ní Sasa?
- Mínístà, Kọ̀wé fipò rẹ sílẹ̀ tàbí kí o dákẹ́ tí ò kó bá wá àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tó sọnù- ọmọ Nàìjíríà
Bakan naa ni Femi Falana sọrọ lori agbara ara ilu lati ṣe iwọde ati ipa ọlọpaa lati daabo bo wọn lasiko iwọde naa.
O menuba ona ti wọn n gba sin maalu lasiko aye Awolọwọ ni eyi ti wọn kọle fawọn ẹran ọsin naa ni.
- Ẹ fura o! Nàìjíríà ń pín lọ díẹ̀ díẹ̀ rèé- Abdulsalami
- Gbenga Daniel kò ṣẹ̀ṣẹ̀ kúrò ní PDP, ó kàn fi ẹ̀ka APC kan sílẹ̀ lọ sí òmíràn ni- PDP
- Ọ̀nà láti dín paǹtí irin kù ló sọ mí di agbẹ́rinlére aláṣeyọrí- Oladele Ogbeyemi
- Ìjì òtútù pa èèyàn 21 ní Amẹ́ríkà, ẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ míràn ń dojúkọ ìṣoro àìsíná ẹ̀lẹ́ńtíríkì
- Wo iye kọ́ńdọ́mù táwọn ọmọ Nàìjíríà fi ń ṣara rindin lọ́dún
O ni bayii, eeyan lo n yago loju popo fun Maalu nigba ti malu ti n jaye ọlọba ninu igboro.
Ni ipari Femi Flana fa awọn gomina ipinlẹ Yoruba leti pe aabọ ọrọ la n sọ fọmọluwabi
- Philip ẹni ọdún 99 tó jẹ́ ọkọ Ọbabìnrin Elizabeth ń gba ìtọ́jú lọ́wọ́ nílé ìwòsàn
- Wo ẹ̀bùn owó tabua tí gbajúgbajà oníṣòwò kan fún bàbá "Lórí Irọ́"
- Àìṣàtìpó rí ló ń da Ejiogbe láàmú, àsìkò ìjọba tèmi ló dé- Alhaji Mukaila Auxilliary
- Akẹ́kọ̀ọ́ ọmọ ọdún mẹ́rìnlá mú ìbọn ìléwọ́ lọ ilé ìwé láti yìín lu olùkọ́ tó ní kó gé irun orí rẹ̀
- Ṣé lóòtọ́ ni omidan yìí ya wèrè ní kété tí ọ̀rẹ́kùnrin rẹ̀ ní òun fẹ́ fi ṣaya?