Kò ṣeé má gbọ̀ọ́

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Ko se ma gbọọ
Kò ṣeé má gbọ̀ọ́

Hmmm, ibọn AK-47 to le lẹgbẹrun mẹta ni wọn lo ti dawati bayii lawọn olu ileeṣẹ ọlọpaa ilẹ wa

Ṣe wọn rin lọ ni?

Ẹka to n mojuto iṣẹ ọba nile igbimọ aṣofin lo kede bẹẹ

Nibo la o wa'bọn si bayii

Alukoro ọlọpaa Naijiria, Muyiwa Adejobi ti sọ bo ṣe jẹ

lllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllll

Ẹ ma ra data tabi pe lori foonu yin fun wakati mẹta lojumọ

Ṣe o n waini mi ni, iru ọwọ wo niyẹn

Ẹgbẹ oṣiṣẹ, NLC lo kuku ni kawọn eeyan bẹrẹ ẹ loni Ọjọbọ lati fẹhonu han fawọn ẹlẹrọ ibaraẹni sọrọ to fi owo kun owo ipe

Afi suuru, igba wo la o wa ṣe bẹẹ da

;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;;

A ko ni i yee beere fun kootu Sharia nilẹ Yoruba

Eyin wo?

Igbimọ to ga julọ fun ofin Sharia atawọn musulumi tọrọ kan ni wọn wi bẹẹ o

Wọn ni bawo lawọn yoo ṣe dakẹ nigba ti mọṣalaṣi nla to wa nilẹẹ Yoruba le lẹgberun mẹrindinlogun.

Tawọn musulumi ko si rọwọ mu ninu ijọba Tinubu yii