Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Àkójọpọ̀ àwọn ìròyìn káàkiri Nàìjíríà tí kò ṣe é má gbọ̀ ọ́.
Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Hmm, iku tun ti doro, Akọrin ẹmi, Rukayat Gawat ti dagbere faye

Haaa, se ki n se ọmọ Ahaji Aremu Gawat to dawati ni ọdun mejila sẹyin?

Bẹẹni, oun ni a gbọ pe o jade laye ni owurọ oni

Ikunlẹ Abiyamọ o, A fi ki Olorun gba wa lọwọ iku ojiji to wọpọ laarin awọn olorin

Ọpọ ẹbi, ọrẹ ati awọn akẹgbẹ ti se idaro oloogbe naà, tó wọ kaa ilẹ sun nirọlẹ oni

E kan si oju opo BBC.com/Yoruba lati mọ bi eto isinku oloogbe naa se waye

Gbajumọ olokoowo nni, Aliko Dangote, ti gba Ijọba apapọ nimọran lati yọ owo iranwọ ori epo patapata

Ki lawọn anfaani to wa ninu yiyọ owo iranwọ naa?

Aliko Dangote ni igbesẹ naa se koko fun agbega ọrọ aje Naijria

Ẹ kan si oju opo BBC.com/yoruba lati mọ ọ̀pọ̀ anfaani ti Dangote sọ pe o wa ninu yiyọ owo iranwọ ori epo

Ijọba ipinlẹ Osun ti mu adikun ba iye ọjọ ti awọn oṣiṣẹ yoo ma wa sibi iṣẹ laarin ọsẹ kan

Kan si oju opo BBC.com lati mọ iye ọjọ ti awọn oṣiṣẹ yoo fi wa si bi iṣẹ

Aworan