Ko ṣee ma gbọọ

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Ko ṣee ma gbọọ
Ko ṣee ma gbọọ

Gbogbo ipa ni mo n sa lati ri i pe ijinigbe ati iṣekupani ko waye mọ nilẹ Yoruba

Aarẹ ọna Kaka ilẹ Yoruba, Iba Gani Adams, lo ṣalaye bẹẹ fun BBC.

Iba sọ pe oun ti n pe awọn gomina ilẹ Yoruba lati jẹ kawọn ṣe ipade pọ lori awọn ẹgbẹ Boko Haram nilẹ Yoruba

Ṣaa, Kakanfo Adams ti sọ ohun ti yoo ṣẹlẹ sawọn ẹgbẹ naa bi wọn ko ba filẹ Yoruba silẹ kia

Ki lo ni yoo ṣẹlẹ?

\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\

Mi o jẹbi ẹsun ipaniyan ti ẹ fi kan mi .

Akọrin ẹmi, Timileyin Ajayi to jẹwọ pe oun ṣa Salome Adaidu, ọrẹbinrin rẹ pa lo sọ bẹẹ ni kootu.

Ana ọjọ Aje ni Timileyin foju han nile ejo giga ipinle Nasarawa.

Niwaju Adajọ Simon Aboki ni ti Timileyin ti won ba ori Salome lọwọ rẹ lẹyin to kun un tan ti loun ko jẹbi.

Wo ohun to ṣẹlẹ ni kootu loju opo BBC. COM/ YORUBA

,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,

Èèyàn to le lẹgbẹrun lọna igba lo ti padà sí Gaza bayii lẹ́yìn àdéhùn jógun-ó-mí láàrín Israel àti Hamas

Wa a wo bi omije ṣe gba oju gbogbo wọn nigba ti wọn ri ile wọn to ti dahoro lẹyin ogun.

Ki wa lo kan fun wọn ni Gaza bayii?