Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Aarẹ Bola Tinubu ti paṣẹ igbedide ẹṣọ aṣọbode lorilẹ ede kọọkan to w ani ECOWAS

lati wo gbogbo igbegidina to wa laarin awọn orilẹede naa

lojuna ati mu igbokegbodo, awọn araalu ati okoowo maa lọ ni irọwọrọsẹ

Aṣoju Naijiria ni ECOWAS, Musa Nuhu sọ awọn ti bẹrẹ pẹlu ẹnubode Seme ati Badagry

xxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxx

Ọdọmọbinrin kan, Helen Kayode ti ko si gbaga ọlọpaa ni Ekiti

Fẹsun pe o parọ pe awọn agbebọn kan ji oun gbe

Ti wọn si ti oun mọ ile kan loju ọna Iworoko si Ado-Ekiti

Amọ agbẹnusọ ileesẹ ọlọpaa Ekiti, Sunday Abutu sọ pe ile ọkunrin ni Helen wa lorumọju ọjọ naa

xxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxx

Njẹ o mọ pe obinrin ti de ipo poopu ri?

Irọ ni o!

Iroyin ni sẹnturi kẹsan-an ni Obinrin Joan pa orúkọ dà di John tó si darí ìjọ Àgùdà pẹ̀lú orúkọ Póòpù John VIII

Ki aṣiri to tu pé John tó ń jẹ́ kìí ṣe John ọkùnrin bíkòṣe Joan

Bawo wa laṣiri ṣe tu?

Fun ẹkunrẹrẹ

Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́