Kò ṣeé má gbọ̀ọ́

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Ko ṣee ma gbọọ
Kò ṣeé má gbọ̀ọ́

Ẹgbẹ awọn ọlọpaa fẹyinti Naijiria n binu o.

Oni ọjọ Aje gan-an ni wọn tẹ pẹpẹ ifẹhonuhan l'Abuja.

Fifi opin si ilana owo ifẹyinti, Contributory Pension Scheme (CPS) ati awọn nnkan mi-in ni iwọde naa da le lori.

Ki ni CPS?

Lọ si BBC.Com/ Yoruba lati mọ eyi ati ohun ọga agba ọlọpaa Naijiria, Kayode Egbetokun, sọ.

Llllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllll

Mo n gbọ pe wọn ti fagile idanwo WAEC ọdun 2025 yii.

Ṣe nitori atẹjade kan to gbode lori ayelujara?

Bẹẹ ni.

Atẹjade naa sọ pe awọn ibeere kan ti lu sita kawọn akẹkọọ to ṣedanwo naa loṣu karun-un.

Ki ni WAEC waa wi?

Ọga agba lẹka WAEC, Moyosola Adesina, sọ pe atẹjade yii ko wa latọdọ awọn.

Kan si oju opo wa fun ọjọ ti esi idanwo naa yoo jade.

,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,

Ni Kenya

Wọn fẹsun jijẹ agbesunmọmi ati nini nnkan ija oloro kan ajafẹtọọ ọmọniyan, Boniface Mwangi.

Iyẹn lẹyin iwọde tako ijọba loṣu to kọja, nibi ti eeyan mọkandinlogun ti ku.

Ọpọ igba ni Mwangi ti dero ahamọ nitori iwọde tako ijọba Kenya.

Fun ẹkunrẹrẹ.