Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Èsì ìbò gómìnà ìpínlẹ̀ Edo tí INEC kéde ní èèrú nínú, mi ò gbà á wọlé
Dakun, se o papa gbe apoti ibo lẹyin o rẹyin ni?
Ki se emi o, oludije sipo Gomina labẹ asia ẹgbẹ oṣelu PDP, Asue Igbodalo lo sọ bẹẹ
Bakan naa, Gomina Ahmadu Fintiri to jẹ alaga igbimọ ipolongo ibo fun PDP
Ni Ajọ INEC ti tapa sofin to n ri si ọrọ eto idibo ni Naijiria pẹlu bi o ṣe kede oludije APC
Ọrọ pọ lẹnu Asue Igbodalo ati ẹgbẹ oṣelu PDP, ẹ kan si opo bbc.com/yoruba fun ẹkunrẹrẹ
xxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxx
Ikunlẹ abiyamọ o
O le ni ọgọrun un eeyan lo ti padanu ẹmi wọn nibi ibugbamu ado oloro to waye ni guusu orilẹede Lebanon
Koda o le ni ọọdurun eeyan mii to tun farapa yanayana lasiko ikọlu naa
Ninu atẹjade kan ti ajọ eleto ilera lorilẹede naa fi lede fun akọroyin
Kede pe pupọ awọn to farapa lo jẹ obinrin ati ọmọde
Ẹkunrẹrẹ iroyin naa wa loju opo BBC.COM/YORUBA
