Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 1

A o gba kọmọ Naijiria to ba fẹ wa si orilẹ ede wa lo ju oṣu mẹta lọ mọ

Orilẹ ede wo niyẹn

Ijọba Amẹ́rika lo kede bẹẹ ninu atunṣe ofin gbigba fisa ti wọn ṣẹṣẹ gbe jade

Ṣe Naijiria ṣẹ wọn ni?

Amẹrika ni igbesẹ naa waye lati gbẹsan nnkan ti Naijiria n ṣe fawọn eeyan orilẹ ede oun

xxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxx

Ajọ to n ri si eto idanwo wiwọ ile giga, JAMB

Ti kede pe, o kere tan, maaki aadọjọ ni akẹkọọ to ba fẹ wọ ile ẹkọ giga lọdun yii gbọdọ gba ninu idanwo UTME

JAMB ni lẹyin ipade awọn ọga agba ilẹ giga ni ifẹnuko naa waye

Ati pe ọdun mẹrindinlogun ni gbedeke ọjo ori fẹni to ba fẹ wọ ile ẹkọ giga

xxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxx

Njẹ o ti ẹ mọye akasọ ti ẹni ti yoo jẹ Olubadan gbọdọ gun lẹyin to ba jẹ Mọgaji ile wọn?

Mo maa n gbọ ti wọn maa n sọ pe wọn n to ni amọ ọrọ naa ko ye mi dabi alara

Fun ẹkunrẹrẹ awọn akasọ naa nipele nipele