Kò ṣeé má gbọ̀ọ́
Godswill Apakbio di ọwọ mi mu, o si paroko si mi pe oun fẹ ba mi ṣere ifẹ
Ah! Nibo lo ti pade olori ile igbimọ aṣofin Naijiria to fi di ọ lọwọ mu?
Emi kẹ, Sẹnetọ Natasha Akpoti ti wọn da duro nile igbimọ aṣofin l'Abuja lo ṣalaye bẹẹ fun BBC
Oya gbe simi leti
O ni ile aṣofin naa n gbiyanju lati pa ohun mọ agogo oun lẹnu,w ni wọn ṣe da oun duro
______________________________________________
Ọwọ ọlọpaa ipinlẹ ti tẹ awọn ọlọkada to n ṣe agbodegba fun awọn ajinigbe
Kọmisọna ọlọpaa nipinlẹ naa, Alfried Afolabi sọ fun awọn akọroyin pe
Awọn ọlọkada naa lo maa n ba awọn ajinigbe ṣo oju popo ti wọn ba fẹ ṣoṣẹ
Lọ sọju opo wa lati ka iyoku iroyin naa
______________________________________________
O kera ran, ọọdunrun eeyan ati ọgbọn lo ti padanu wọn ni Gaza lẹyin ti awọn ọmọ ogun Israel ju do oloro si Gaza Strip
Iroyin ni asiko ti awọn eeyan n ji saari lọwọ ni ado oloro bẹrẹ si n rọ bii ojo lati oju ofurufu
Fun ẹkunrẹrẹ