Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Awuwuye lori aba ofin owo ori tuntun ni Naijiria
Kekere kọ, duro na, ṣe gbogbo awọn ọlọja kekeke naa yoo maa sanwo ori bayii?
Rara o, ẹnikẹni ti owo to n ri ko ba to miliọnu kan NAIRA lọdun kan lọdun ko ni sanwo ori o
Ma laagun jina, lo sori ikanni BBC Yoruba fun alaye kikun lori ọrọ naa
Ori lo mọṣẹ aṣela lo difa fun akẹkọọgboye fasiti to n kiri mọin-mọin
Ko lo n sọ lẹnu ti o dun yii, nibo lẹni naa wa?
Arakunrin kan Gideon Kupolati akẹkọọ gboye fasiti ilu Ilorin lo sọ fun BBC Yoruba pe
ipele kẹta loun wa lẹnu eto ẹkọ oun nigba toun bẹrẹ si ni fi kootu kiri mọin-mọin
Ko lo sun debẹ gan-an?
Kan soju opo BBC Yoruba fun ẹkunrẹrẹ
Aṣe loootọ ni pe ko si ohun t’ọkunrin le ṣe t’obinrin o le ṣe
Bẹẹ nio, Arabinrin Netumbo Nandi-Ndaitwah ti di aarẹ obinrin akọkọ orilẹede Namibia
Lẹyin iburawọle rẹ, Nandi-Ndaitwah yoo di Aarẹ obinrin keji nilẹ adulawọ lẹyin
Aarẹ Samia Suluhu Hassan Tanzania


