Kò ṣe é má gbọ̀ ọ

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Àkójọpọ̀ àwọn ìròyìn káàkiri Nàìjíríà tí kò ṣe é má gbọ̀ ọ́.
Kò ṣe é má gbọ̀ ọ

Hmmmmmm, orin wo la a fẹẹ kọ si ti epo to tun lewo bayii, o su mi o?

Ma jẹ ko su ọ o, ṣe o ko ti i gbọ nipa imọran ti Dangote gba awọn alagbata epo ni?

Ewo ni ti Dangote ninu ọrọ ?

Aliko Dangote ti ni ko ni si tito ra epo mọ ni Naijiria ti awọn alagbata ba le maa ra epo lọwọ oun

xxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxx

Mo gbọ pe Aarẹ America, Joe Biden, pe Aarẹ Tinubu

Bẹẹ ni?

Ki ni wọn jọ sọ? O da mi loju pe bi nnkan ṣe ri nilẹ yii ni Aarẹ Amerika tori ẹ pe aarẹ tiwa.

Iroyin okeere, bi o din kan, a le kan. Iwọ naa lọ si bbc.com/yoruba fun ẹkunrẹrẹ ohun ti wọn jọ sọ

Gbas-gbos mi-in ma ti n ṣẹlẹ l’Ogbomoso laarin Oba Olaoye Ghandi atawon Musulumi

Won ni Kabiyesi gba ilẹ mọṣalaaṣi fawọn oniṣẹṣe lati fi kọ ṣọọbu.

Iyẹn tun ga o, ki waa ni Kabiyesi wi

Aafin Soun ṣalaye ọrọ, wọn ni onilẹ lo làre

Oo si la a ko ye mi yeke.

Kan si BBC.Com/ Yoruba

Aworan Kò ṣe é má gbọ̀ ọ