Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Awọn adura yii ma tuni lara
Bẹẹ ni o, ṣebi wọn adura tuni lara jepe lọ
Eyi ni BBC News Yoruba fi tọ awọn alufaa lọ lati bẹrẹ ọdun tuntun pẹlu iwure
O si jẹ n gbọ diẹ si
Tara ṣaṣa kan si oju opo bbc.com/yoruba
Njẹ o mọ pe bi awa ṣe n ṣe pọṣinṣin ọdun tuntun ko kan awọn orilẹ ede kan rara
Ọrọ rẹ ko ye mi, la a han mi
Ṣo o mọ pe awọn orilẹ ede bii China, Ethiopia atawọn mii kii ṣe ọdun tuntun lọjọ Kiini oṣu Kiini ti a n ṣe yii?
Ehn ẹhn loootọ?
Ẹkunrẹrẹ awọn orilẹ ede naa loju opo bbc.com/yoruba
A maa ṣe idasilẹ ti yoo mojuto ọwọngogo ounjẹ atawọn oogun lọdun 2025
Eyi ni ileri aarẹ Tinubu ninu ọrọ akọsọ rẹ fawọn ọmọ Naijiria lọdun tuntun
Tinubu ni oun mọ ilakaka tawọn araalu n la kọja lori ounjẹ ati oogun
Ati pe ko to di ipari oṣu kẹfa ni ileeṣẹ naa yoo gberasọ
