'Lọ́dún 2026, ẹyẹ á ké bí ẹyẹ, ọmọ èèyàn á fọhùn bí ọmọ èèyàn', Soun Ogbomosho, Ọba Ghandi Olaoye ṣe ìwúre ọdún
'Lọ́dún 2026, ẹyẹ á ké bí ẹyẹ, ọmọ èèyàn á fọhùn bí ọmọ èèyàn', Soun Ogbomosho, Ọba Ghandi Olaoye ṣe ìwúre ọdún
"Gbogbo awa ọmọ kaarọ oo jiire, pataki, gbogbo ọmọ ilu Ogbomosho, ...mo fẹ fi da yin loju pe ọkan wa o n gbadura fun yin ni gbogbo igba pe Ọlọrun a ṣe e ni ọdun abo fun gbogbo wa; ẹyẹ á ké bí ẹyẹ, ọmọ èèyàn á fọhùn bí ọmọ èèyàn"
Eyi ni diẹ lara awọn iwure ti Oba Ghandi Ọlaoye, to jẹ Ṣọun ti ilu Ogbomoshọ wu fun gbogbo ọmọ Naijiria pẹlu bi wọn sẹ wọ inu ọdun tuntun 2026.
Ninu iwure naa lo ti gbadura pe ọdun 2026 yii, ko ni jẹ ọdun ibanujẹtabi aṣeti fun koowa.