You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Pásítòͅ kú lásìkò ààwèͅ ogójì oͅjóͅ tó gbà bíi ti Jesu
Pasitoͅ kan lorileͅede Mozambique ti ku lasiko to n gbiyanju lati gba aaweͅ ati adura fun ogoji oͅjoͅ bii ti Jesu Kristi.
Pasitoͅ Francisco Barajah to jeͅ oludasileͅ ijoͅ Santa Trindade Evangelical church lo ku ni ileewosan ni ilu Beira leͅsan.
Pasitoͅ oͅun ni woͅn ni o gba aaweͅ ati adura fun oͅjoͅ marundinloͅgboͅn lai tii jeͅun tabi mu omi, to si ti ru patapata de ibi pe ko lee rin moͅ.
Eͅni oͅdun moͅkandinlogoji ni arakunrin naa ki o to ku.
Iroyin ni awoͅn moͅleͅbi ati ojulumoͅ ni woͅn kan an nipa fun lati loͅ si ileewosan fun itoͅju to peye.
‘’Ko si eͅjeͅ lara pasitoͅ moͅ nigba ti woͅn gbe de ileewosan’’
Arakunrin Barajah ni awoͅn dokita ni o ti ni aisan eͅjeͅ ti ko to, acute anaemia nigba to de ileewosan, ti awon kindinrin reͅ si ti koͅ isͅeͅ sileͅ.
Leͅyin naa ni woͅn fun ni awoͅn eroja asͅaraloore serum, ki ara reͅ le ji pepe.
Amoͅ igbiyanju lati fun ni ounjeͅ jijeͅ lo gba ibeͅ loͅ, to si dagbere fun aye.
Pasitoͅ naa lo tun jeͅ olukoͅ imoͅ Faranse ni ilu Messica ati Manica ni Zimbabwe.
Nindun pastoͅ, woͅn ni ki n sͅe igba akoͅkoͅ ni yii ti ti pasitoͅ oͅhun n gba aaweͅ, amoͅ kii peͅ to bayii.
Amoͅ aburo pasitoͅ naa ni ohun ko gba ohun ti awoͅn dokita soͅ gboͅ nipa iku pasitoͅ oͅhun, to si ni aisan eͅjeͅ to kere – low blood pressure lo pa eͅgboͅn oun.
Igba akoͅkoͅ koͅ niyii ti awoͅ eniyan yoo gbe igbeseͅ lati gba aaweͅ ati adura bii ti Jesu Kristi fun ogoji oͅjoͅ.
Ni oͅdun 2015, arakunrin kan ku ni Zimbabwe leͅyin to gbadura ati aaweͅ fun oͅgboͅn oͅjoͅ.
Bakan naa ni oͅdun 2006 ni iwadii iku fihan pe aaweͅ gbigba lo pa obinrin kan ni ilu London.