Oͅkòͅ òfúrufú tó jábóͅ ní Tanzania gbẹ̀mí ènìyàn 19

Ọkọ ofurufu to ja sinu omi ni Tanzania

Oríṣun àwòrán, CHARLES MWEBEYA TBC

Oͅkoͅ ofurufu kan ti abeͅle ti jaboͅ lorileͅede Tanzania, ti eniyan moͅkandinlogun si ti gbeͅmi mi.

Iroyin ni oͅkoͅ naa jaboͅ si alagbalugbu omi Lake Victoria lasiko to n gbiyanju lati baleͅ si agbegbe Bukoba.

O kere tan eniyan meͅrinlelogun ninu awoͅn meͅtalelogoji to wa ninu oͅkoͅ ofurufu naa lo jajaboͅ.

Geͅgeͅ bi oͅroͅ ti eͅka to n risi oͅroͅ ofurufu Pricision Airline sͅe sͅoͅ, awoͅn meͅrinlelogun ni woͅn ti doola eͅmi woͅn. Igbiyanju sͅI n loͅ loͅwoͅ lati doola eͅmi awoͅn eniyan Bakan naa ni woͅn koͅkoͅ soͅ pe awoͅn awakoͅ ofurufu mejeeji naa koͅkoͅ wa laaye.

Ti woͅn si gbiyanju lati ba awoͅn osͅisͅeͅ soͅroͅ ni abeͅle lati inu oͅkoͅ ofurufu naa.

Amoͅ olotu ijoͅba orileͅede Tanzania ni o sͅeese ki awoͅn mejeeji ti gbeͅmi mi.

Oͅkoͅ ofurufu naa lo jaboͅ si eͅgbeͅ adagun omi to ti ko jina si papakoͅ ofurufu naa.

Awoͅn adoola eͅmi naa ni woͅn ko sinu omi, ti woͅn si beͅreͅ si ni yoͅ awoͅn eniyan ti woͅn ha sinu oͅkoͅ ofurufu naa.

Titi di asiko yii, igbiyanju si n loͅ loͅwoͅ lati doola eͅmi awoͅn eniyan ti woͅn sͅI ha sinu oͅkoͅ ofurufu naa.