Àlàyé lórí ìrólágbára ìjọ̀ba ìbílẹ̀ wà nínú Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Àlàyé lórí ìrólágbára ìjọ̀ba ìbílẹ̀ wà nínú Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Laipẹ yii ni ile ẹjọ to ga julọ ni Naijiria dajọ pe, ki agbara ati aṣẹ lori owo to n wọle si apo awọn ijọba ibilẹ, pada sọwọ wọn.
Ṣaaju idajọ naa, ọpọ awọn gomina lo n dari bi awọn ijọba ibilẹ sẹ n na owo wọn, ti wọn si tun n yan alaga fun wọn.
Lati igba igba ti idajọ naa ti waye si ni awọn gomina kan ti n fi apa jaamu lori rẹ.
Bẹẹ ni awọn ọmọ Naijiria kan n dun nu si idajọ ọhun.
Alaye ree ninu Ko ṣe e ma gbọ ti ọsẹ yii.