Kò ṣeé má gbọ̀ọ́
Ile igbimọ aṣofin agba Naijiria tilẹkun mọ Sẹneto Natasha Akpoti-Uduaghan, wọn o jẹ ko wọle.
Oni ọjọ Iṣẹgun ti Sẹnetọ to n ṣoju Aarin Gbungbun Kogi naa balẹ sile igbimọ ni awọn ẹṣọ tilẹkun mọ ọ
Koda, Aisha Yusuf, ajafẹtọọ ọmọniyan atawọn to tẹle Natasha yari pẹlu oyinbo kabiti.
Nibo lo wa ja si?
Ka a loju opo wa.
………………………………………………………..
Bina n jo bojo n rọ, PDP ni mi o.
Gomina ipinlẹ Osun, Ademola Adeleke lo sọ bẹẹ lẹyin ipade pẹlu awọn alẹnulọrọ PDP Osun lanaa.
Adeleke ni gbogbo ẹgbẹ ti fa oun kalẹ lati dupo gomina lẹẹkẹji.
Wọn si ti buwọ lu Tinubu bii aarẹ titi di 2027
Alaye wa ni BBC.COM/Yoruba.
<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<<
Kaasa, wọn o ma ti i ri ẹgbẹlẹgbẹ nnkan ija ogun to poora nileeṣẹ ologun ilẹ Ghana lọdun to kọja.
Aarẹ Ghana, John Mahama, kede pe ewu n bẹ pẹlu awọn nnkan aabo ilu to poora naa.
O ni ko ma lọ jẹ ọwọ awọn oniṣẹ ibi to le ko ba aabo ilu ni wọn bọ si.
Ewo wa ni ṣiṣe bayii?

