Kò ṣeé má gbọ̀ọ́

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Ko see ma gboo
Kò ṣeé má gbọ̀ọ́

Awọn Agbébọn tún ṣọṣẹ́ ni Plateau, araalu mẹrinla ati ọlọ́pàá kan ni wọn tun pa nijọba ibilẹ Bokkos.

Alaga igbimọ to n ri si alaafia niluu Bokkos, Kefas Mallai, ṣalaye pe

lasiko tawọn ara abule Chirang n bọ lati ọja lawọn agbebọn ọhun dawọn lọna ti wọn si yinbọn pa wọn

Bawo wa ni tọlopaa to ku ṣe jẹ?

Alaye wa lori ikanni BBC Yoruba

'''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''

Njẹ o mọ pe iwulo ilu kọja ijo lasan.

Bunmi gbọ o

BBC Yoruba wa nibi ajọdun Ayangalu to n lọ lọwọ niluu Ile ifẹ.

Nibi ti Ọọniriṣa, Oba Adeyeye Ogunwusi ti lewaju awọn to n n filu kona mọ iṣọkan, alaafia ati aṣa.

Ọna wo ni wọn n gba ṣe eyi gan na?

Lọ ka a loju opo wa.

''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''

Lonii ọjọ kẹẹdọgbọn, oṣu Keje ọdun ni ayajọ awọn obinrin to ni orirun jẹ ilẹ Africa

BBC yanna-na awọn akọni obinrin ti orukọ wọn n milẹ titi kaakiri agbaye

Bii agbaọjẹ olorin Angelique Kijio, akọrin takafufee Tems, Folorunso Alakija

Awon yooku nkọ?