Wo fídíò bí ayẹyẹ ìgbéyàwó Ọbabìrin Elizabeth ṣe wáyé lọ́dún 1947
Ogunjọ oṣu Kọkanla, ọdun 1947 ni Ọmọba Philip gbe ọmọbabirin Elizabeth ni iyawo.
Inu gbọgan Westmisnter Abbey ni eto igbeyawo naa ti waye.
Ko din ni ẹgbẹrun meji eeyan to wa ninu gbọgan naa lọdun naa lọhun.
Nigba ti nnkan bii ẹgbẹrun lọna ọgọrun eeyan mii wa niwaju aafin lati foju ganni tọkọ-taya tuntun naa.









