Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Ìsẹ̀lẹ̀ jákèjádò orílẹ̀èdè àgbáyé láàárín ìṣẹ́jú kan.
Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Erin wo, ajanaku sun bi oke

Owá Obokun ti ile ljesa, Oba Gabriel Adekunle Aromolaran kookanla ti waja Asiwaju gbogbo omo bibi ijesa lapapo Olayinka Fasuyi lo kede pe ale ojoru ojo

Kokànlá osu Kèsán vi ni kabiyesi naa darapo mawon baba nla won

K'Eledua dele feni ire

Àwon wo tún lolópàá 'Supernumerary Police' àti pé kí ni isé won láwüjo?

Ma ma foyinbon pe ara re lolee, agbenuso ileese lorileede Naijiria, Olumuyiwa Adejobi ti salaye iyato to wa laarin irufe olopaa Supernumerary Police atawon olopaa taraalu maa n ri lojoojumo, koda aso won gan an yato Tie ba fe mo si nipa awon olopaa vii, e kan si oju opo BBC.COM/Yoruba

Ojo a ba ku la a dere, eniyan o sunwon laaye

Ta lo tun ku o?

Akorin emi Dele Gold lo ma jade laye

Haaa, sebi losu to lo ni Aduke Gold toun naa jolorin emi dagbere faye ni?

Bee ni, ko sire nibe, gpo akegbe Dele Gold bi Akinlabi Mayor, Alayo Melody singer ati Wonder Doyin Kujore lo ti n sedaro eni ire to lo Lana Ojoru ni a gbo pe Dele Gold jade laye levin aisan ranpe

Kan soju opo BBC.COM/Yoruba fun ekunrere

Aworan Ko se e ma gbọ ọ