Kò ṣeé má gbọ̀ọ́

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Akọjọpọ iroyin ti ko ṣee ma gbọọ
Kò ṣeé má gbọ̀ọ́

Aarun Diphtheria ti gbẹmi akẹkọọ kan, ti awọn kan si tun wa nileewosan

Diph... kinni, ewo lẹ tun n pe bẹẹ?

Aarun ọhun ni iroyin sọ pe o bẹ silẹ nile ẹkọ King's College nipinlẹ Eko laipẹ yii

Kọmisanna eto ilera nipinlẹ Eko, Akin Abayomi sọ pe awọn ti n fun awọn akẹkọọ yooku ni abẹrẹ ajẹsara

Bawo ni mo ṣe le dena aarun diphtheria ọhun?

Kan si bbc.com/yoruba

MMMMMMMMMMMMMMMMMMMMMMMMMMMMMMMMM

Ẹ fura o, ayederu kọndọọmu ti gbode

Ajọ NAFDAC lo kede bẹẹ lẹyin ti wọn kẹẹfin ayederu gbajugbaja kọdọọmu kan

Bawo wa ni mo ṣe fẹẹ da ojulowo mọ bayii o?

Ma laagun jina, kan si bbc.com/Yoruba

mmmmmmmmmmmmmmmmmmmmmmmmmmmm

Ìjọba Amẹrika ti ṣi áàpù fàwọn tí kò ní ìwé ìgbélùú láti padà s'orílẹ̀èdè wọn

Olori eto aabo Amẹrika, Kristi Noem, sọ pe awọn to ba lo aapu naa lati fi Amẹrika silẹ yoo le wọle pada

Eyi n waye lasiko ti ijọba aarẹ Trump n fi awọn to n gbe lorilẹede naa lọna aitọ, sọko pada sorilẹẹde abinii wọn