Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Gbọ na, báwo ni biliọnu mọkanlelaadọ naira ṣe pòórá nínú owó tí ìjọba ń yawọn akẹ́kọ̀ọ́ ní Naijiria?
ibeere nla, ajọ ICPC to n gbogun ti iwa ajẹbanu ni Naijiria
ti bẹrẹ iwadii lẹyin ti iroyin sọ pe awọn ile ẹkọ giga kan n yọ lara owo to yẹ ko tẹ awọn akẹkọọ naa lọwọ
Ẹkunrẹrẹ wa lori ikanni BBC Yoruba
''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''
ṣe lóòótọ́ ni okowo CBEX ti bẹ̀rẹ̀ padà ní Naijiria?
Bẹẹ la a bi ni o, BBC Yoruba ti kan sawọn eeyan kan ti wọn si n ṣe CBEX labẹ aṣọ
Ki ni wọn wa sọ?
Kan soju opo BBC.Com/Yoruba, ti o ba fẹ mọ
''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''
Iná sọ lọ̀jà fóònù ní Ilorin,
dúkìá olówo iyebíye ati ọ̀pọ̀lọpọ̀ fóònù jóná ninu ijamba ina ọhun
ina mọnamọna ni a gbọ pe o fa ijamba ọhun


