Kí ló máa ń ṣẹlẹ̀ sí ọpọlọ nígbà tí ẹ̀dá bá kú?

Àkọlé fídíò, Kí ló máa ń ṣẹlẹ̀ sí ọpọlọ nígbà tí ẹ̀dá bá kú?
Kí ló máa ń ṣẹlẹ̀ sí ọpọlọ nígbà tí ẹ̀dá bá kú?

Iku nikan lo daju nile aye. Amọṣa ki lo n ṣẹlẹ si ẹda ṣaaju iko ati lẹyin iku rẹ?

Ọrọ iku ati ohun to n ṣlẹ lawọn akoko diẹ ṣaajuati awọn akoko totẹle asiko ti eeyan jade laye yii ku fun ọpọlọpọ kayeefi ati ibeere ti ọpọ eeyan ṣi n wa idahun si.

Aworan eeyan kan to n rin lọ ninu oju ọna gbayawu kan.

Amọṣa o dabi ẹni pe idahun si ọkan lara awọn ibeere yii pe ki lo maa n ṣẹlẹ si ọpọlọ eniyan lẹyin iku ti jade pẹlu bayii.

Ko fi bẹẹ si iwadii imọ ijinlẹ Sayẹnsi lori ọrọ yii ṣaaju asiko yii titi di ọdun diẹ sẹyin.

Amọṣa, eyi ti n yi pada.