Kí ló dé tó jẹ́ pé ènìyàn nìkan ló ń sọ̀rọ̀ nínú gbogbo ohun tí Elédùmarè dá?

Àkọlé fídíò, Kí ló dé tó jẹ́ pé ènìyàn nìkan ló ń sọ̀rọ̀ nínú gbogbo ohun tí Elédùmarè dá?
Kí ló dé tó jẹ́ pé ènìyàn nìkan ló ń sọ̀rọ̀ nínú gbogbo ohun tí Elédùmarè dá?

Ọpọ lo ti le maa woye pe, ki lo de to fi jẹ pe ninu gbogbo ohun ti adẹda da lofurufu, lori ilẹ koda titi kan inu omi, ko si eyi to da lati sọrọ yatọ̀ si ọmọ eniyan.

Lootọ ọpọ awọn amuyẹ miran wa to wa lara eniyan ti awọn ẹrankọ abẹmi miran ni, amọ, ọrọ sisọ ko si ninu wọn bi o ti wulẹ ko mọ.

Iroyin ti BBC News gbe tọ yin wa yii ṣe iwadii si ipilẹ ọrọ sisọ fun eniyan, titi kan bi awọn ede akọkọ ti ọmọ eniyan gbọ ti o si sọ ṣe ri gan an ati ohun to jẹ ọrọ akọkọ