You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Wo àwọn ìwé ìrìnà tó lágbára jù lágbayé lọ́dún 2023
Iwadi ajọ agbaye to risi irina lati orilẹede kan si ibi kan, Henley & Partners ti #se afihan awọn iwe irina to lagbara ju lagbaye lọdun 2023.
ikede ajọ ọhun safihan awọn orilẹede mẹta lati ilẹ Asia ti iwe irina wọn fun ẹnikẹni lati lọ si orilẹede to ba wu wọn ni gbogbo agbaye.
Wo awọn orilẹede ti iwe irina dara ju lọdun 2023.
1. Japan (Orilẹede 193)
2. Singapore, South Korea (Orilẹede 192)
3. Germany, Spain (Orilẹede 190)
4. Finland, Italy, Luxembourg (Orilẹede 189)
5. Austria, Denmark, Netherlands, Sweden (Orilẹede 188)
6. France, Ireland, Portugal, United Kingdom (Orilẹede 187)
7. Belgium, New Zealand, Norway, Switzerland, United States, Czech Republic (Orilẹede 186)
8. Australia, Canada, Greece, Malta (Orilẹede 185)
9. Hungary, Poland (Orilẹede 184)
10. Lithuania, Slovakia (Orilẹede 183)
Wo awọn orilẹede ti iwe irina ku diẹ kato fun
Ọpọ awọn orilẹede lo fun awọn eeyan ni anfani wọ ilu pẹlu disa ọfẹ.
Awọn re.
102. North Korea (Orilẹede 40)
103. Nepal, Palestinian territory (Orilẹede 38)
104. Somalia (Orilẹede 35)
105. Yemen (Orilẹede 34)
106. Pakistan (Orilẹede 32)
107. Syria (Orilẹede 30)
108. Iraq (Orilẹede 29)
109. Afghanistan (Orilẹede 27)
Ipo wo ni awọn orilẹede Adulawọ wa ninu awọn iwe irina ti Henley gbejade?
Awọn orilẹede mẹta to n lewaju ni ilẹ adulawọ ti iwe irina naa wọn lagbara ni
Ipo kini ni ilẹ adulawọ ni Seychelles, to si ipo mọkandinlọgbọ ninu iwadi Henley lori iwe irina to lagbara julọ lagbaye. Iwe irin orilẹede yii le wọ orilẹede 153
Ipo keji ni orilẹede South Africa nilẹ adulawọ, to oun si wa ni ipo mẹtalelaadọta ninu iwadii Henley. Iwe irin orilẹede yii le wọ orilẹede 153
Botswana lo wa ipo kẹta, ti awọn si wa ni ipo mẹtalelọgọta lagbaye . . Iwe irin orilẹede yii le wọ orilẹede 87
Ghana wa ni ipo ọgbọrin lagbaye, ti Iwe irin wọn si le wọ orilẹede 65.
Ipo mẹtadinlọgọrun ni orilẹede Naijiria wa