Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́ - 4 Owewe, 2024
Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́ - 4 Owewe, 2024
Ẹgbẹ oṣiṣẹ ni Naijiria, NLC, ti yari mọ ijọba apapọ lọwọ lori afikun jala epo bẹntiro
Aarẹ ẹgbẹ naa, Joe Ajaero ni ọdalẹ ni Tinubu latari bo ṣe yẹ adehun awọn lori afikun owo epo naa
O wa rọ ileeṣẹ Aarẹ lati da owo epo ọhun pada si iye to wa tẹlẹ lai fọta pe
Njẹ o tilẹ mọ iye igba ti ijọba ti fikun owo epo ni Naijiria?
Oya gbe simi leti
Lọ soju opo BBC Yoruba fun ẹkunrẹrẹ
Ara meeriri, obinrin pe oro, oro si dahun
Irọ ni o!
Ootọ ni o!
Ṣebi awọn agba sọ pe awo Egungun ni obinrin le se, awo Gẹlẹdẹ ni obinrin le wo, bi obinrin ba fi oju kan Oro, Oro yoo gbe
Obinrin ti pe oro niluu Iyoko, to wa nipinlẹ Isakete lorilẹede Benin Republic, ti oro si n da lohun
Ẹhn...ẹhn
Fun alaye ohun to ṣẹlẹ, irufẹ oro to wa ati ohun ti yoo ṣẹlẹ si obinrin to ba foju kan oro