Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Idajọ ita gbangba ni mo fẹ lori iku ọmọ mi o
Taa lo sọ bẹ.
Iya akẹkọọ ti awọn ọlọpaa yinbọn pa niluu Ilorin lo n beere fun idajọ ododo
Abudulqoyum Bamidele, akẹkọọ ile ẹkọ gbogbonise Kwaram Poly
Ni awọn afurasi ọlọpaa ma sekupa lojiji
Ki wa ni esi ileeṣẹ ọlọpaa lori iṣẹlẹ
Kan si oju opo BBC.com/Yoruba to ba fẹ mọ
Ori Ade ma dero ọgba ẹwọn Kuje o
Haaa, ka ma ri ni Paul wi
Oba Taofeeq Osunmakinde, Obawore ti ile ifetuntun, ni ile ẹjọ ni ki o lọ ma gba atẹgun lọgba ẹwọn Kuja
Oba ati eeyan mẹrin mii ni wọn jẹjẹ lori ẹsun wiwa goolu ni ọna ti ko ba ofin mu
Dakun, ki o ma wa jẹ ti ọba alade bayii
To ba fẹ mọ kan si oju opo BBC.com/Yoruba
