Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Ajọ to n gbọ ẹhonu ibo ti da ẹjọ ti ẹgbẹ oṣelu Action Alliance pe tako gomina ipinlẹ Edo, Monday Okpebholo nu
Lọjọru ni igbimọ naa ni ẹjọ ti AA àti Adekunle Omoaje naa pe ko lẹsẹ nilẹ ati pe
Omoaje ko laṣẹ lati pe eto idibo naa lẹjọ nitori ko kopa nibẹ
Ki wa ni abọ ẹjọ ti PDP pe tako ibo gomina naa?
Kan soju opo bbc Yoruba
xxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxx
Omi tuntun ru, ẹja tuntun sọ lodo nile iṣẹ to n ri si ọrọ epo ni Naijiria, NNPC
Bi aarẹ Tinubu ṣe yọ Mele Kyari nipo alaga ajọ naa to si fi Bashiru Ojulari rọpo rẹ
Tinubu tun yọ gbogbo awọn alabaṣiṣẹ igbimọ naa to si fawọn mii rọpo wọn
Ta wa ni Bashiru Ojulari yii?
Kan soju opo bbc.com/Yoruba lati ka ẹkunrẹrẹ iroyin nipa rẹ
xxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxx
Ọpọ eeyan lorilẹede Somalia lo n tutọ soke foju gba a
lẹyin ti wọn ba ọdun mẹjọ ti wọn ti n wa fun oṣu mẹfa nile Shehu kan to sọ pe oun ti fẹ n iyawo
Ileeṣẹ ọlọpaa ni awọn ti gba ọmọ naa kalẹ ati pe Shehu naa ti w ani ahamọ
