Èyí làlàyé ohun tó ń fa ìwà ipá nínú ìdílé, àti bí o ṣe lè dẹ́kun rẹ̀
Èyí làlàyé ohun tó ń fa ìwà ipá nínú ìdílé, àti bí o ṣe lè dẹ́kun rẹ̀
Ọpọlọpọ iṣẹlẹ lo maa n bi ija ati aigbọra-ẹni ye laarin ololufẹ meji.
Ọpọ idile ni iwa ipa tit u ka ti o si ti sọ awọn ọmọ di alaini baba tabi alainiya.
Gẹgẹbi ijọba ipinlẹ Eko ṣe sọ pe I'sẹlẹ ipa to din diẹ lẹgbẹrun mẹjọ lo waye laarin oṣu mọkanla sẹyin ni ipinlẹ Eko.