Kò ṣeé má gbọ̀ọ́

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Ko ṣe ma gbọọ
Kò ṣeé má gbọ̀ọ́

Aaye ọpẹ ti n yọ fun Oriyomi Hamzat àti olorì Naomi lori ẹjọ ti wọn n jẹ nipa iku ọmọ marundinlogoji n'Ibadan

Ṣe loootọ?

Nibi igbẹjọ to waye ni kootu lonii ọjọ Aje ni Adajọ Ladiran Akintola ti fi aaye ọsẹ meji silẹ fawọn olujẹjọ lati ṣepade pẹlu awọn obi to padanu ọmọ

Ki ni yoo waa ṣẹlẹ lẹyin ipade

Ẹkunrẹrẹ wa loju opo wa

Bbbbbbbbbbbbbbbbbbbbbbbbbbbbbbbbbbbbbbbbbbbbb

,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,

Nasir El-Rufai,gomina Kaduna tẹlẹ ma ti fi ẹgbẹ APC silẹ

Oni ọjọ Aje ni El-Rufai loun yọwọ lọrọ APC lẹyin iṣẹ takun-takun.

O loun ko le tẹsiwaju pẹlu ẹgbẹ APC mọ nitori iṣesi wọn tako demokresi.

Ati pe APC ko mọ ibi ti ọlọkọ n wa wọn lọ lagbo oṣelu

SDP ni El-Rufai ba lọ bayii?

,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,

3)Iwadii ti bẹrẹ lori iku Alaga Miyetti Allah ipinlẹ Kwara, Idris Sakaina tawọn kan yinbọn pa

Iwaju ile rẹ l'Oke Oyi ni wọn pa a si lalẹ Satide ijẹta

Alukoro ọlọpaa Kwara, Adetoun Adeyemi, sọ pé àwọn bá ọta ìbọn márùn-ún níwájú ilé náà.

Aworan iroyin ko ṣee ma gbọọ