Wo àwọn oníjàkadì inú ẹrọ̀fọ̀ tó wá di ògo àgbáyé
Wo àwọn oníjàkadì inú ẹrọ̀fọ̀ tó wá di ògo àgbáyé
Ninu ẹrẹ kan ni kampala, ere ijakadi kan a maa waye ti wọn n pe ni Soft ground Wrestling, eyi ti a le tu lede Yoruba si, ijakadi ori ilẹ rirọ.
Ko si ina yinrinyinrin eleyi to jẹ ara amuyẹ ere idaraya ijakadi igbalode, awọn ọdọmọkunrin ati ọdọmọbinrin- ti wọn jẹ ọkunrin mejidinlọgọrin ati obinrin mọkandinlọgbọn ni iye – ti n mi ilẹ titi kaakiri agbaye.
Okiki wọn si ti kan si de ọdọ awọn alaṣẹ ere idaraya ijakadi igbalode, WWE bii Cody Rhodes ẹni to ṣẹṣẹ jẹjẹ laipẹ gbagede ijakadi kan fun wọn lati ṣe atilẹyin fun wọn.






