Wo bí o ṣe lè fètò sọ́mọ bíbí láì lo ògùn tàbí abẹ́rẹ́ rárá

Àkọlé fídíò, Wo bí o ṣe lè fètò sọ́mọ bíbí láì lo ògùn tàbí abẹ́rẹ́ rárá
Wo bí o ṣe lè fètò sọ́mọ bíbí láì lo ògùn tàbí abẹ́rẹ́ rárá

Bi ọrọ aje ṣe n dẹnukọle ti ọrọ idile nini n di ṣebootimọ yii awn mẹkunu n wa ọna lati jẹgba dun ibalopọ ṣugbọn ti ko ni la ipenija fifikun iye ẹnu ti wọn n bọ ni idile wọn nipa bibi ọ̀mọ.

Lootọ aaye ifetosọmọbibi wa, amọ ọpọ ni kii fẹ lo awọn ilana oyinbo bi abẹẹrẹ, tabi oogun ati iṣẹ abẹ nitori awọn ohun ti wọn foju wo gẹgẹ bi atunbọtan rẹ lagọ ara.

Amọṣa awọn ọna kan wa nipa kikiyesi ọjọ si ọjọ ninu osu kan si ikeji, lati le fi mọ awn akoko to dara lati ni ibalopọ ti ko si ni di oyun rara.

Alaye wa ninu fidio yii