Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Kikọ ni mimọ
Ewo lẹ tun n kọ
Ajọ EFCC lo tu àṣírí ile ẹkọ tawọn ọmọ ilẹ̀ òkèèrè ti n kọ awọn ọmọ Naijiria ni Yahoo ṣiṣe
Haa, nibo niyẹn.
Ninu ile alaja meje kan to wa ni Victoria Island l'Eko lọwọ ti tẹ awọn ajoji tiṣa ọhun ati àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ti àpapọ̀ wọn jẹ 792
7 kinni?
Ẹkunrẹrẹ wa ni bbc.com/yoruba
================================================
Njẹ o mọ pe Ọjọru ọla ni Aarẹ Tinubu yoo gbe aba iṣuna 2025 lọ sile igbimọ aṣofin.
Bẹẹ ni,lẹyin atunṣe igbẹyin ti wọn ṣe lọjọ Iṣẹgun.
O fẹẹ mọ iye owo ti Naijiria fẹẹ na lọdun to n bọ bí àti ọ̀nà tí wọ́n ó gba ríi?
====================================================
Iyawo dun lọsingin, ọkọ tun mi gbe
Laaago meloo niyẹn.
Ba mi ka lọ loju opo BBC Yoruba, ko o ri tọkọ-taya Mulero Akintunde
Ti wọn n ṣalaye aṣiri to gbe igbeyawo wọn duro lati ọdun marunlelọgọta
Ati ọna abayọ fawọn ọdọ iwoyi ti igbeyawo wọn ki i tọjọ.

